Róòmù 9:29 BMY

29 Àti bí Ìsáià ti wí tẹ́lẹ̀:“Bí kò ṣe bí Olúwa àwọnỌmọ-ogun ti fi irú-ọmọ sílẹ̀ fún wa,àwa ìbá ti dàbí Sódómù,a bá sì ti sọ wá dàbí Gòmórà.”

Ka pipe ipin Róòmù 9

Wo Róòmù 9:29 ni o tọ