Àwọn Ọba Kinni 10:19 BM

19 Ìtẹ́ náà ní àtẹ̀gùn mẹfa, ère orí ọmọ mààlúù sì wà lẹ́yìn ìtẹ́ náà. Ère kinniun wà ní ẹ̀gbẹ́ kinni keji ibi tí wọn ń gbé apá lé lára ìtẹ́ náà.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 10

Wo Àwọn Ọba Kinni 10:19 ni o tọ