Àwọn Ọba Kinni 10:20 BM

20 Ère kinniun mejila wà lórí àwọn àtẹ̀gùn mẹfẹẹfa, meji meji lórí àtẹ̀gùn kọ̀ọ̀kan, ní ẹ̀gbẹ́ kinni keji àtẹ̀gùn náà; kò sí ìjọba orílẹ̀-èdè kankan tí ó tún ní irú ìtẹ́ náà.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 10

Wo Àwọn Ọba Kinni 10:20 ni o tọ