Àwọn Ọba Kinni 16:18 BM

18 Nígbà tí Simiri rí i pé ọwọ́ ti tẹ ìlú náà, ó lọ sí ibi ààbò tí ó wà ninu ààfin, ó tiná bọ ààfin, ó sì kú sinu iná;

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 16

Wo Àwọn Ọba Kinni 16:18 ni o tọ