Àwọn Ọba Kinni 16:23 BM

23 Ní ọdún kọkanlelọgbọn tí Asa, ọba Juda ti wà lórí oyè, ni Omiri gorí oyè ní Israẹli. Ó sì jọba fún ọdún mejila. Ìlú Tirisa ni ó gbé fún ọdún mẹfa àkọ́kọ́.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 16

Wo Àwọn Ọba Kinni 16:23 ni o tọ