Àwọn Ọba Kinni 17:10 BM

10 Elija bá lọ sí Sarefati. Bí ó ti dé ẹnu ọ̀nà ibodè ìlú náà, ó rí obinrin opó kan tí ń wá igi ìdáná. Ó wí fún obinrin yìí pé, “Jọ̀wọ́ lọ bá mi bu omi wá kí n mu.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 17

Wo Àwọn Ọba Kinni 17:10 ni o tọ