11 Bí ó ti ń lọ bu omi náà, Elija tún pè é pada, ó ní, “Jọ̀wọ́ bá mi mú oúnjẹ díẹ̀ lọ́wọ́ sí i.”
Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 17
Wo Àwọn Ọba Kinni 17:11 ni o tọ