Àwọn Ọba Kinni 17:19 BM

19 Elija dáhùn pé, “Gbé ọmọ náà fún mi.” Ó bá gba òkú ọmọ náà lọ́wọ́ rẹ̀, ó gbé e gun orí òkè ilé lọ sinu yàrá tí ó ń gbé, ó sì tẹ́ ẹ sórí ibùsùn rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 17

Wo Àwọn Ọba Kinni 17:19 ni o tọ