Àwọn Ọba Kinni 17:20 BM

20 Ó képe OLUWA, ó ní, “OLUWA, Ọlọrun mi, kí ló dé tí o fi jẹ́ kí irú ìdààmú yìí bá obinrin opó tí mò ń gbé ọ̀dọ̀ rẹ̀ yìí, tí o jẹ́ kí ọmọ rẹ̀ kú?”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 17

Wo Àwọn Ọba Kinni 17:20 ni o tọ