21 Elija bá na ara rẹ̀ sórí ọmọ yìí nígbà mẹta, ó sì ké pe OLÚWA, ó ní, “OLUWA Ọlọrun mi, jẹ́ kí ẹ̀mí ọmọ yìí tún pada sinu rẹ̀.”
Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 17
Wo Àwọn Ọba Kinni 17:21 ni o tọ