Àwọn Ọba Kinni 19:5 BM

5 Ó dùbúlẹ̀ lábẹ́ igi náà, ó sì sùn. Lójijì, angẹli kan fi ọwọ́ kàn án, ó sì wí fún un pé, “Dìde kí o jẹun.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 19

Wo Àwọn Ọba Kinni 19:5 ni o tọ