6 Ó wò yíká, ó sì rí ìṣù àkàrà kan, ati ìkòkò omi kan lẹ́bàá ìgbèrí rẹ̀. Ó jẹun, ó mu omi, ó sì tún dùbúlẹ̀.
Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 19
Wo Àwọn Ọba Kinni 19:6 ni o tọ