Àwọn Ọba Kinni 20:37 BM

37 Wolii yìí rí ọkunrin mìíràn, o sì bẹ̀ ẹ́ pé, “Lù mí.” Ọkunrin yìí lù ú, lílù náà pọ̀ tóbẹ́ẹ̀ tí ó fi pa á lára.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 20

Wo Àwọn Ọba Kinni 20:37 ni o tọ