Àwọn Ọba Kinni 21:20 BM

20 Nígbà tí Ahabu rí Elija, ó bi í pé, “O tún ti rí mi kọ́, ìwọ ọ̀tá mi?”Elija bá dá a lóhùn pé, “Bẹ́ẹ̀ ni, mo tún ti rí ọ; nítorí pé o ti fa ara rẹ kalẹ̀ láti ṣe iṣẹ́ burúkú níwájú OLUWA.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 21

Wo Àwọn Ọba Kinni 21:20 ni o tọ