Àwọn Ọba Kinni 21:21 BM

21 OLUWA ní òun óo jẹ́ kí ibi bá ọ, òun óo pa ọ́ rẹ́, òun ó sì run gbogbo ọkunrin tí ń bẹ ninu ìdílé rẹ, ati ẹrú ati ọmọ.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 21

Wo Àwọn Ọba Kinni 21:21 ni o tọ