Àwọn Ọba Kinni 3:1 BM

1 Solomoni gbé ọmọ Farao, ọba Ijipti níyàwó, ó fi bá ọba Farao dá majẹmu àjọṣepọ̀ láàrin wọn. Solomoni mú iyawo náà wá sí ìlú Dafidi títí tí ó fi parí ààfin rẹ̀ ati ilé OLUWA tí ó ń kọ́, ati odi Jerusalẹmu tí ó ń mọ lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 3

Wo Àwọn Ọba Kinni 3:1 ni o tọ