Àwọn Ọba Kinni 3:2 BM

2 Oríṣìíríṣìí pẹpẹ ìrúbọ ni àwọn eniyan tẹ́ káàkiri, tí wọ́n sì ń rúbọ lórí wọn, nítorí wọn kò tí ì kọ́ ilé OLUWA nígbà náà.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 3

Wo Àwọn Ọba Kinni 3:2 ni o tọ