Àwọn Ọba Kinni 4:34 BM

34 Àwọn eniyan sì ń wá láti oniruuru orílẹ̀ èdè, ati láti ọ̀dọ̀ àwọn ọba ní gbogbo ayé, tí wọ́n ti gbúròó nípa ọgbọ́n rẹ̀, wọn á wá tẹ́tí sí ọgbọ́n rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 4

Wo Àwọn Ọba Kinni 4:34 ni o tọ