Àwọn Ọba Kinni 5:1 BM

1 Nígbà tí Hiramu, ọba Tire, gbọ́ pé Solomoni ni ó gun orí oyè lẹ́yìn baba rẹ̀, ó rán oníṣẹ́ sí i; nítorí ọ̀rẹ́ ni òun ati Dafidi, wọ́n sì fẹ́ràn ara wọn.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 5

Wo Àwọn Ọba Kinni 5:1 ni o tọ