Àwọn Ọba Kinni 9:12 BM

12 Ṣugbọn nígbà tí Hiramu ọba wá láti Tire tí ó rí àwọn ìlú tí Solomoni fún un, wọn kò tẹ́ ẹ lọ́rùn rárá.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 9

Wo Àwọn Ọba Kinni 9:12 ni o tọ