Àwọn Ọba Kinni 9:13 BM

13 Ó bi Solomoni pé, “Arakunrin mi, irú àwọn ìlú wo ni o fún mi yìí?” Ìdí nìyí tí wọ́n fi ń pe ilẹ̀ náà ní Kabulu títí di òní olónìí.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 9

Wo Àwọn Ọba Kinni 9:13 ni o tọ