Joṣua 11:12 BM

12 Joṣua gba gbogbo ìlú àwọn ọba náà, ó kó àwọn ọba wọn, ó fi idà pa wọ́n, gẹ́gẹ́ bí Mose iranṣẹ OLUWA ti pàṣẹ fún un.

Ka pipe ipin Joṣua 11

Wo Joṣua 11:12 ni o tọ