13 Ṣugbọn àwọn ọmọ Israẹli kò sun èyíkéyìí ninu àwọn ìlú tí wọ́n kọ́ sórí òkítì níná, àfi Hasori nìkan ni Joṣua dáná sun.
Ka pipe ipin Joṣua 11
Wo Joṣua 11:13 ni o tọ