Joṣua 14:2 BM

2 Gègé ni wọ́n ṣẹ́, tí wọ́n fi pín in fún ẹ̀yà mẹsan-an ati ààbọ̀ ninu ẹ̀yà àwọn ọmọ Israẹli, gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pàṣẹ fún Mose.

Ka pipe ipin Joṣua 14

Wo Joṣua 14:2 ni o tọ