Joṣua 14:3 BM

3 Nítorí pé Mose ti fún àwọn ẹ̀yà meji ati ààbọ̀ ní ìpín tiwọn ní òdìkejì odò Jọdani, ṣugbọn kò pín ilẹ̀ fún àwọn ẹ̀yà Lefi.

Ka pipe ipin Joṣua 14

Wo Joṣua 14:3 ni o tọ