Joṣua 15:46 BM

46 láti Ekironi títí dé etí òkun Mẹditarenia, ati gbogbo àwọn ìlú tí wọ́n wà lẹ́bàá Aṣidodu pẹlu àwọn ìletò wọn.

Ka pipe ipin Joṣua 15

Wo Joṣua 15:46 ni o tọ