Joṣua 15:47 BM

47 Aṣidodu, pẹlu àwọn ìlú ati àwọn ìletò rẹ̀; Gasa, pẹlu àwọn ìlú ati àwọn ìletò rẹ̀ títí dé odò Ijipti, ati etí òkun Mẹditarenia, pẹlu agbègbè rẹ̀.

Ka pipe ipin Joṣua 15

Wo Joṣua 15:47 ni o tọ