Joṣua 2:2 BM

2 Àwọn kan bá lọ sọ fún ọba Jẹriko pé, “Àwọn ọkunrin kan, lára àwọn ọmọ Israẹli, wá sí ibí ní alẹ́ yìí láti ṣe amí ilẹ̀ yìí.”

Ka pipe ipin Joṣua 2

Wo Joṣua 2:2 ni o tọ