Joṣua 2:3 BM

3 Ọba Jẹriko bá ranṣẹ sí Rahabu ó ní, “Kó àwọn ọkunrin tí wọn dé sọ́dọ̀ rẹ jáde wá, nítorí pé wọ́n wá ṣe amí ilẹ̀ yìí ni.”

Ka pipe ipin Joṣua 2

Wo Joṣua 2:3 ni o tọ