Joṣua 21:2 BM

2 ní Ṣilo ní ilẹ̀ Kenaani, wọ́n sọ fún wọn pé, “OLUWA ti pàṣẹ láti ẹnu Mose pé kí wọ́n fún wa ní ìlú tí a óo máa gbé ati pápá oko fún àwọn ẹran ọ̀sìn wa.”

Ka pipe ipin Joṣua 21

Wo Joṣua 21:2 ni o tọ