Joṣua 21:3 BM

3 Nítorí náà, gẹ́gẹ́ bí àṣẹ OLUWA, àwọn ọmọ Israẹli fún àwọn ọmọ Lefi ní àwọn ìlú ati pápá tí ó yí wọn ká, ninu ilẹ̀ ìní wọn.

Ka pipe ipin Joṣua 21

Wo Joṣua 21:3 ni o tọ