Joṣua 24:25 BM

25 Joṣua bá dá majẹmu pẹlu àwọn eniyan náà ní ọjọ́ náà, ó sì ṣe òfin ati ìlànà fún wọn ní Ṣekemu.

Ka pipe ipin Joṣua 24

Wo Joṣua 24:25 ni o tọ