Joṣua 24:26 BM

26 Ó kọ ọ̀rọ̀ náà sinu ìwé òfin Ọlọrun, ó gbé òkúta ńlá kan, ó sì fi gúnlẹ̀ lábẹ́ igi Oaku, ní ibi mímọ́ OLUWA,

Ka pipe ipin Joṣua 24

Wo Joṣua 24:26 ni o tọ