Joṣua 9:16 BM

16 Nígbà tí ó di ọjọ́ kẹta tí wọ́n ti bá àwọn eniyan náà ṣe àdéhùn, ni wọ́n gbọ́ pé nítòsí wọn ni wọ́n wà, ati pé aládùúgbò ni wọ́n.

Ka pipe ipin Joṣua 9

Wo Joṣua 9:16 ni o tọ