Joṣua 9:17 BM

17 Àwọn ọmọ Israẹli bá gbéra ní ọjọ́ kẹta, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí ka àwọn ìlú wọn. Àwọn ìlú náà ni: Gibeoni, Kefira, Beeroti ati Kiriati Jearimu.

Ka pipe ipin Joṣua 9

Wo Joṣua 9:17 ni o tọ