Samuẹli Kinni 10:24 BM

24 Samuẹli bá wí fún àwọn eniyan náà pé, “Ẹni tí OLUWA yàn nìyí. Kò sí ẹnikẹ́ni láàrin wa tí ó dàbí rẹ̀.”Gbogbo àwọn eniyan náà kígbe sókè pé, “Kí ọba kí ó pẹ́.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 10

Wo Samuẹli Kinni 10:24 ni o tọ