26 Saulu náà bá pada lọ sí ilé rẹ̀ ní Gibea. Àwọn akọni ọkunrin bíi mélòó kan tí Ọlọrun ti fi sí ní ọkàn bá Saulu lọ.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 10
Wo Samuẹli Kinni 10:26 ni o tọ