Samuẹli Kinni 10:27 BM

27 Ṣugbọn àwọn oníjàngbọ̀n kan dáhùn pé, “Báwo ni eléyìí ṣe lè gbà wá?” Wọ́n kẹ́gàn rẹ̀, wọn kò sì mú ẹ̀bùn wá fún un, ṣugbọn Saulu kò sọ̀rọ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 10

Wo Samuẹli Kinni 10:27 ni o tọ