Samuẹli Kinni 2:5 BM

5 Àwọn tí wọ́n rí oúnjẹ jẹ lájẹyó ríti di ẹni tí ń fi ara wọn ṣọfà nítorí oúnjẹ,ṣugbọn àwọn tí ebi ti ń pa tẹ́lẹ̀ rí tí ń jẹ àjẹyó.Àgàn ti di ọlọ́mọ meje,ọlọ́mọ pupọ ti di aláìní.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 2

Wo Samuẹli Kinni 2:5 ni o tọ