Samuẹli Kinni 2:6 BM

6 OLUWA ni ó lè pa eniyan tán,kí ó sì tún jí i dìde;òun ni ó lè múni lọ sinu isà òkú,tí ó sì tún lè fani yọ kúrò níbẹ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 2

Wo Samuẹli Kinni 2:6 ni o tọ