Samuẹli Kinni 2:7 BM

7 OLUWA ni ó lè sọni di aláìní,òun náà ni ó sì lè sọ eniyan di ọlọ́rọ̀.Òun ni ó ń gbéni ga,òun náà ni ó sì ń rẹ eniyan sílẹ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 2

Wo Samuẹli Kinni 2:7 ni o tọ