Samuẹli Kinni 22:2 BM

2 Gbogbo àwọn tí wọ́n wà ninu ìpọ́njú, ati àwọn tí wọ́n jẹ gbèsè ati àwọn tí wọ́n wà ninu ìbànújẹ́ sá wá sọ́dọ̀ rẹ̀. Gbogbo wọn jẹ́ irinwo (400) ọkunrin, ó sì jẹ́ olórí wọn.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 22

Wo Samuẹli Kinni 22:2 ni o tọ