Samuẹli Kinni 22:3 BM

3 Dafidi kúrò níbẹ̀ lọ sí Misipa ní ilẹ̀ Moabu, ó sọ fún ọba Moabu pé, “Jọ̀wọ́ jẹ́ kí baba ati ìyá mi dúró lọ́dọ̀ rẹ títí tí n óo fi mọ ohun tí Ọlọrun yóo ṣe fún mi.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 22

Wo Samuẹli Kinni 22:3 ni o tọ