10 Dafidi ní, “OLUWA, Ọlọrun Israẹli, èmi iranṣẹ rẹ gbọ́ pé Saulu ti pinnu láti wá gbógun ti Keila ati láti pa á run nítorí mi.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 23
Wo Samuẹli Kinni 23:10 ni o tọ