Samuẹli Kinni 23:11 BM

11 Ǹjẹ́ àwọn alàgbà Keila yóo fà mí lé Saulu lọ́wọ́? Ṣe Saulu yóo wá gẹ́gẹ́ bí mo ti gbọ́? Jọ̀wọ́, OLUWA Ọlọrun Israẹli, fún mi ní èsì.”OLUWA sì dáhùn pé, “Saulu yóo wá.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 23

Wo Samuẹli Kinni 23:11 ni o tọ