12 Dafidi tún bèèrè pé, “Ǹjẹ́ àwọn alàgbà Keila yóo fà mí lé e lọ́wọ́?”OLUWA dáhùn pé, “Bẹ́ẹ̀ ni, wọn yóo fà ọ́ lé e lọ́wọ́.”
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 23
Wo Samuẹli Kinni 23:12 ni o tọ