27 Nígbà náà ni oníṣẹ́ kan wá sọ fún Saulu pé, “Pada wá kíákíá, nítorí pé àwọn ará Filistia ti gbógun ti ilẹ̀ wa.”
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 23
Wo Samuẹli Kinni 23:27 ni o tọ