28 Nítorí náà, Saulu pada lẹ́yìn Dafidi, ó sì lọ bá àwọn ará Filistia jà. Nítorí ìṣẹ̀lẹ̀ náà ni wọ́n ṣe ń pe òkè náà ní Àpáta Àsálà.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 23
Wo Samuẹli Kinni 23:28 ni o tọ