Samuẹli Kinni 25:42 BM

42 Ó yára gun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ̀, òun pẹlu àwọn iranṣẹbinrin rẹ̀ marun-un, wọ́n sì tẹ̀lé àwọn iranṣẹ Dafidi lọ, Abigaili sì di aya Dafidi.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 25

Wo Samuẹli Kinni 25:42 ni o tọ