Samuẹli Kinni 27:3 BM

3 Wọ́n ń gbé Gati pẹlu àwọn ará ilé wọn. Àwọn aya Dafidi mejeeji, Ahinoamu ará Jesireeli ati Abigaili ará Kamẹli, opó Nabali, sì wà pẹlu rẹ̀ níbẹ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 27

Wo Samuẹli Kinni 27:3 ni o tọ